1 July 2017

Hafiz Adewuyi

Durosoke by Olamide - Lyrics in English

DUROSOKE - Rap song by Olamide - English translation (English in bold)
------------------------------------------------------------

INTRO
Take it outside; Basket

Take it inside; Koroba 
Take it inside, Basket


Olamide rapper Image
Olamide
(By Emily Nkanga (Own work) [CC BY-SA 4.0 (http://creativecommons.org/licenses/by-sa/4.0)], via Wikimedia Commons)

HOOK
Dem be feeling us 
They were admiring us

And now them they famz just to be with us 
And now, they're feigning familiarity just to be with us

A lówó, a lẹ́nu, a dẹ̀ mọ̀'yàn o
We have money, we are influential, we know important people

A jayé orí wa, ko dẹ̀ kan'yan o, yeh
We enjoy our lives, and it doesn't concern anyone

See the money now

We weigh, we no dey count the money now
We weigh the money, we don't count it any longer

We fully loaded ready on this now

The moneneneneni running out, yeh
Jargon


CHORUS
Sé kó wálẹ̀; kó dúró sókè 
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ̀; kó dúró sókè
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ̀; kó dúró sókè
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ̀; kó dúró sókè
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò; kó dúró sóke ò ò ò
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò; kó dúró sóke ò ò ò
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò; kó dúró sóke ò ò ò
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò; kó dúró sóke ò ò ò
Should it come down? Let it stay up


TRACK 1
**repeated coughs**
Bahdo, baddest guy ever liveth
Great guy, the greatest guy who ever lived

Édímastà lọmọ o, kò ń ṣe prífẹ̀t
He is a headmaster, he's not a prefect

School wo ló ti wá náà, OSÚ àb'Ífẹ̀?
What school did she come from; Ogun State University or University of Ife

Àbí Bábcọ̀ck, kílódé t'ọ́n bìf e
Or is it Babcock University? Why are they hating on her?

Mosúnmọ́lá, ṣo mọ lọ́lípọ̀p lá
Mosunmola, do you know how to lick a lollipop?

Òwun tún dà, òwun tún rè, óyá Tọ́lá
Where is she now? Here she is. Tola, it's time

Kílón ṣe ẹ́ ná, yé ma fimí pọ́p kọ́là
What is wrong with you; stop taking my attention for granted

Ó fẹ́ máa p'ajá lọ́bọ fún mi, ṣé mo kọlà
She wants to deceive me, do I look stupid to you?

JJC kọ́ l'àwọn eléyìí, ọ̀gá'dé
These ones are not novices, young man

ÚNÌLAG ò jìnà sí lé'wa, gbàgbé
UNILAG is not far from our house, forget it

Mo ti rọ́mọ, mo ti rọ́mọ yakpa
I have seen pretty chicks, I have seen so many pretty chicks

Awúsá, fúlàní, yíbò àti tákpà
From the Hausa, Fulani and Tapa tribes

Àwọn ọmọ mi, àwọn ọmọ mi ń'Lọ́ńdọ̀n
My pretty chicks, my pretty chicks in London

Àwọn ọmọ mi l'Ámẹ́ríkà, àwọn stúbbọ̀rn
My pretty chicks in America; the stubborn ones

Àwọn t'ọ́n ma ń twẹ̀rk, lórí YóúTubè
Those ones who twerk on YouTube

I know you love me, I love you too

Stórì yíì ti fẹ́ ma lọ́, má ṣe báyìí now
This story is getting complicated; please don't act this way

Ìgbà wo lo dé to fẹ́ máa lọ, má ṣe báyìí now
When did you just arrive that you're getting ready to leave; please don't do this

Oò rọ́kọ̀, oò rọ́kọ̀ ta ṣí wọlé
Can't you see; can't you see the big cars we came in

Ojú e ló mọ́ọ ṣe, wàá r'áwọn ọmọ ta ma ṣí lọlé
You will witness in awe, the calibre of chicks we will go home with

Wọ́n fọwọ́ pa ọ́ lára, ò ń dún míyáwu
You're getting fondled and you are meowing

Ṣ'ọ́lóńgbò ni ọ́ ni, o sì wá ń wò mí l'ójú báwun
Are you a cat? See the way you're staring me down


HOOK
Dem be feeling us
They were admiring us

And now them they famz just to be with us
And now, they're feigning familiarity just to be with us

A lówó, a lẹ́nu, a dẹ̀ mọ̀'yàn o
We have money, we are influential, we know important people

A jayé orí wa, ko dẹ̀ kan'yan o, yeh
We enjoy our lives, and it doesn't concern anyone

See the money now

We weigh, we no dey count the money now
We weigh the money, we don't count it any longer

We fully loaded ready on this now

The moneneneneni running out, yeh
Jargon


CHORUS
Sé kó wálẹ̀; kó dúró sókè
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ̀; kó dúró sókè
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ̀; kó dúró sókè
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ̀; kó dúró sókè
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò; kó dúró sóke ò ò ò
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò; kó dúró sóke ò ò ò
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò; kó dúró sóke ò ò ò
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò; kó dúró sóke ò ò ò
Should it come down? Let it stay up


TRACK 2
Óyá, ẹ ká wọ́'lẹ̀ fún pásítọ̀, ẹ ká wọ́'lẹ̀, ẹ ká wọ́'lẹ̀
Listen up! Drop your hands for the pastor. Drop your hands, drop your hands

Baddest guy ever liveth, hun, òṣé
The greatest guy who ever lived; thank you

Ìpadàbọ̀ ab'ìjàwàrà bí ẹkùn; eh
The return of the lead warrior like a lion

Mo fẹ́ ẹ́ńtá thè placè, óyá ṣ'ílẹ̀kùn; yéè
I want to enter the place; open the door!

Ex-boyfriend ẹ ń ran'jú, òwun náà ń bọ̀ *laughs*
Your ex-boyfriend is getting visibly angry; he is approaching me

Mo dẹ̀ mọ̀'yàn o *laughs*, hmm, Ọlọ́run ń gbọ́
I know important people, hmm, I cross my heart

Mo lè ní kán soó mọ́lẹ̀, kán táyì ẹ̀
I can command them to tie him to the ground, to bind him in ropes

Mo lè ní kán paá láró, kán dáyì ẹ
I can command them to rub him with dye; to dye him

Ṣe b'ọ́n ń báa sọ́ ń'sìnyí, ó ń forí lalẹ̀
They're wooing her politely now, but she's not cooperating

Ó da náà, lálẹ̀yí, á forí balẹ̀
It's okay. This night, she will bow

Wòó; ẹ bámiṣí àwọn ọmọ wólè
Hey! Help me release the chicks

Àwọn ọmọ Cọ́vẹ́nánt, àwọn ọmọ North Amẹ́ríká unì gan ò ní pẹ́ lánd
The Covenant University chicks. Even the North-American-University chicks are about to land

Àwọn ọmọ mi, àwọn ọmọ t'ọ́n blọ́ọ́dy
My chicks, my bloody chicks

Àwọn ọmọ t'ọ́n Ṣhínasà, t'ọ́n tún Ṣhíkọ̀dí
My chicks, the likes of Chinasa and Chikodi

I can't shout, ọ̀rọ́ pọ̀ nínú ìwé kọ́bọ̀
I can't shout; there are too many words in the book of Kobos

Bọ̀dí no be firewood, mi ò dẹ̀ ń ṣe rọ́bọ̀t
The temptations of the flesh are strong and I'm not a robot

Kí ní ti ẹ̀ mọ ń ṣ'èyin ọmọ èkó yìí gan
What is the problem with you Lagos chicks

O sì ń se bí ẹní pé ò rí mi látẹ̀ẹ̀kan
And you're pretending you don't know I've been here all this while

Aní kó rèbàdíì rẹ, o sì wá ń ṣ'akọ
We asked you to shake your derriere, and now, you're strutting and ignoring us

O sì wá ń ṣebí ẹni pé o ò mọ'rú orin tá n kọ
Now, you're pretending not to know the kind of music we sing

Kí ní ń ṣe ẹ́, àb'ọ́ ń gbọ́ Mafadó
What's wrong with you; or don't you hear of Mafado?

O ò ń gbọ́ Vice càrtẹlì, o sì wá ń bragadó; yéébà
Don't you hear about Vice Cartel? And you're still bragging at us!

Àbí ṣọ́ọ̀ṣì dípá laìfù lò ń lọ ni
Or are you a member of the Deeper Life church?

Ọ ọ̀ dá'yàn mọ̀, ṣhíọ̀; ọ ọ̀ mọ bàdóò, shíọ
You don't know important people, shame; you don't know the great guy, shame


HOOK
Dem be feeling us *laughs*
They were admiring us

And now them they famz just to be with us; mi'ì gbọ́
And now, they're feigning familiarity just to be with us; I can't hear you

A lówó, a lẹ́nu, a dẹ̀ mọ̀'yàn o; you say?
We have money, we are influential, we know important people; say what?

A jayé orí wa, ko dẹ̀ kan'yan o, yeh; okay, take it up now
We enjoy our lives, and it doesn't concern anyone; okay take it up now

See the money now; you say?

We weigh, we no dey count the money now; mi'ì gbọ́
We weigh the money, we don't count it any longer; I can't hear you

We fully loaded ready on this now; yéébà

The moneneneneni running out, yeh
Jargon


CHORUS
Sé kó wálẹ̀ (yéébà);  kó dúró sókè (yéébà)
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ̀ (yéébà);  kó dúró sókè (yéébà)
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ̀ (yéébà);  kó dúró sókè (yéébà)
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ̀ (yéébà);  kó dúró sókè (yéébà)
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò (yéébà); kó dúró sóke ò ò ò (yéébà)
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò (yéébà); kó dúró sóke ò ò ò (yéébà)
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò (yéébà); kó dúró sóke ò ò ò (yéébà)
Should it come down? Let it stay up

Sé kó wálẹ ò (yéébà); kó dúró sóke ò ò ò (yéébà)
Should it come down? Let it stay up

OUTRO
Mi ò gbọ́
I can't hear you

If you can't put your hands up, you disappear

Bahdo, baddest guy ever liveth
Great guy, the greatest guy who ever lived

You exit this territory, sharp sharp
You exit this territory immediately

Baddest guy ever liveth is in the building
The greatest guy who ever lived is in the building

Bahdo!
The great guy

Kó dúró sókè, kí ló ń jẹ́ kó wálẹ̀
Let it stay up; what nonsense do you mean by "let it come down"

Bahdo!
The great guy

Ah, they don know
Ah. Now they know!

Subscribe to this Blog via Email :

1 comments :

Write comments
Unknown
AUTHOR
1 July 2017 at 18:45 delete

Funny you.
Well nigerian music is always full of jargon.

Reply
avatar